quarta-feira, 27 de julho de 2016

Orín Òsún



A ri ide gbé o
Omi ro a! wàrá-wàrá omi ro O fi'de se'mo l'Òyó
Omi ro a! wàrá-wàrá omi ro O fi'de se'mo l'owo
Omi ro a! wàrá-wàrá omi ro O fi'de se'mo l'òrun


Òsun e lóolá imolè lóomi Òsun e lòolá
Ayaba imolè lòomi


Yèyé yé olóomi ó, yèyé yé, Olóomi ó
Ayaba balè Òsun Ayaba balè Òsun
Ìyá dò sìn máa gbè ìyá wa oro Ìyá dò sìn máa gbè ìyá wa oro
Igbá ìyawó igbá si Òsun ó réwà Igbá ìyawó igbá si Òsun ó réwà Àwá sin e ki igbá réwà Igbá ìyawó igbá si Òsun ó réwà



Bom dia! Vamos acordar e e agradecer por mais uma manhã.
E que terça-feira, Òsún nos ilumine e Ògún nos guie, nos livrando das maldades do mundo.

Nenhum comentário:

Postar um comentário